Eji Ogbe tabi Ogbe Meji, Bàbá Odu Ifá
Mo ki yin, olólùfẹ́ èdè ati À ṣ à Yorùbá kaakiri ni orílẹ̀-èdè lagbaye. Orúk ọ tèmi ni Adelson Adéwalé de Brito ti ọpọ l ọ́ p ọ̀ ènìyàn m ọ̀ sí Mawo Adelson . Oluk ọ̀ Àgbà èdè ati àṣà Ànàgó ni ìlú Salvador. Olu-ìlú ipinlẹ̀ Baííà ni orílẹ̀-èdè Brasili ìlú Salvador lo n ṣe. M o fẹ́ kí gbogbo eniyan máa gbádura si Ọlọ́run pe ki ìjọba r ẹ̀ de laibikita ìsìn olukaluku wọn nitori wipe Ọlọrun nìkan ṣoṣo wa, Ẹ l ẹ́ da naa gbogbo ènìyàn ati Ẹ l ẹ́ da gbogbo ohun to wa ninu ilè Aye. Olùgbàlà wa kí á tó dá ayé, ati nisinsinyii ati títí ayé ainipẹkun, lailai a ṣ ẹ́ . AMIN. Èjì Ogbè tabi Ogbe Meji, Odu Kini Ifa n ni loni wipe: oju kò kan mi emi kò kan ju ni o difa fún ero pese ti ń l ọ ṣe ọk ọ ìgbín ìgbín ńwá ọk ọ ero pese ńwá ìyàwó àw ọn n mejeeji wá l ọ si ilé alawo ni otootọ ero pese wá bèèrè l ọ́ w ọ́ Ifa wipe nj ẹ́ oun le ni aya ìgbín naa bèèrè l ọ́ w ọ́ alawo r ẹ̀ wipe ńjẹ́ oun le ni ọk ọ awo ń ...