Postagens

IFÁ jẹ́ ohun Ọgbọ́n Ọlọ́run Olódùmarè.

Imagem
  Àwọn Yorùbá gbàgbọ́ wí pé Olódùmarè ló rán Ifá wá láti òde ọ̀run latí wá fi Ọgbọ́n rẹ̀ tún ilé ayé ṣe. Ọgbọ́n, ìmọ̀, àti òye tí Olódùmarè fi fún Ifá ló fún Ifá ní ipò ńlá láàárín àwọn ìbọ ní ilẹ̀ Yorùbá. “A-kéré-finú-ṣọgbọ́n” ni oríkì Ifá. Ọ̀rúnmìlà ni a ṣ aju Ifá nipa ohun gbogbo bi ti ọrun, b ẹ́ ẹ̀ ni li aye . Ìgbàgbọ́ Yorùbá ni wípé ní ìgbà kan rí, Ọ̀rúnmìlà gbé òde-ayé fún ìgbà pípẹ́ kí o tó padà lọ sí Ọ̀rùn. Ní ìgbà tí Ọ̀rúnmìlà fi wà ní ilé ayé, ó gbé Ilé-Ifẹ̀ fún ìgbà péréte. Ṣùgbọ́n ní ìgbà tí Ọ̀rúnmìlà fi wà láyé yìí náà, a tún máa lọ sí òde ọ̀run lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan tí Olódùmarè bá pèé láti wá fi Ọgbọ́n rẹ̀ bá òun tún òde-ọ̀rùn ṣe. Nítorí náà gbáyégbọ́run ni Ọ̀rúnmìlà Ifá ńṣe. Ìtàn sọ fún wa wípé ọmọ mẹ́jọ ni Ọ̀rúnmìlà bí nígbà tí ó wà láyé, nígbà tí ó di ọjọ́ kan ti Ọ̀rúnmìlà ńṣe ọdún ni ọ̀kan nínú àwọn ọmọ yìí tíí ṣe àbíkẹ́hìn pátápátá bá ṣe àfójúdi sí Ọ̀rúnmìlà, ni Ọ̀rúnmìlà bá bínú fi ayé sílẹ̀ lọ sí òde Ọrun. Ni Ọ̀rúnmìlà   ìfá bá relé olókun kòdé mọ́. Ó lẹ́n...

O Odu Ifá Eji Ogbe

Imagem
Saúdo todos os amantes da língua e da cultura iorubá no mundo. Meu nome é Adelson Adéwalé de Brito popularmente conhecido como Mawo Adelson. Professora sênior de língua e cultura Nagô na cidade de Salvador. A capital do estado da Bahia é a cidade de Salvador. Quero que todos orem a Deus para que Seu Reino venha, independentemente de sua religião individual, porque existe apenas um Deus, o Criador de todas as pessoas e o Criador de tudo no mundo. Nosso Salvador antes mesmo da criação do mundo, agora e pelos séculos dos séculos, para todo o sempre. AMÉM A mensagem do Principal do Ifa diz (ontem) é que: oju kò kan mi emi kò kan ju ni o difa fún ero pese ti ń l ọ ṣe ọk ọ ìgbín ìgbín ńwá ọk ọ ero pese ńwá ìyàwó àw ọn n mejeeji wá l ọ si ilé alawo ni otootọ ero pese wá bèèrè l ọ́ w ọ́ Ifa wipe nj ẹ́ oun le ni aya ìgbín naa bèèrè l ọ́ w ọ́ alawo r ẹ̀ wipe ńjẹ́ oun le ni ọk ọ awo ń babalawo awo mejeeji s ọ̀ fún w ọ́ n wípè ki w ọ́ n l ọ rub ọ, ki w ọ́ n si...

Eji Ogbe tabi Ogbe Meji, Bàbá Odu Ifá

Imagem
  Mo ki yin, olólùfẹ́ èdè ati À ṣ à Yorùbá kaakiri  ni orílẹ̀-èdè  lagbaye. Orúk ọ tèmi ni Adelson Adéwalé de Brito ti ọpọ l ọ́ p ọ̀ ènìyàn m ọ̀ sí Mawo Adelson . Oluk ọ̀ Àgbà èdè ati àṣà Ànàgó ni ìlú Salvador. Olu-ìlú ipinlẹ̀ Baííà ni orílẹ̀-èdè Brasili ìlú Salvador lo n ṣe. M o  fẹ́  kí gbogbo eniyan  máa gbádura si Ọlọ́run pe ki ìjọba r ẹ̀ de laibikita ìsìn olukaluku wọn nitori wipe Ọlọrun nìkan ṣoṣo wa, Ẹ l ẹ́ da naa gbogbo ènìyàn ati Ẹ l ẹ́ da gbogbo ohun to wa ninu ilè Aye. Olùgbàlà wa kí á tó dá ayé, ati nisinsinyii ati títí ayé ainipẹkun, lailai a ṣ ẹ́ . AMIN. Èjì Ogbè  tabi Ogbe Meji, Odu Kini Ifa n ni loni wipe: oju kò kan mi emi kò kan ju ni o difa fún ero pese ti ń l ọ ṣe ọk ọ ìgbín ìgbín ńwá ọk ọ ero pese ńwá ìyàwó àw ọn n mejeeji wá l ọ si ilé alawo ni otootọ ero pese wá bèèrè l ọ́ w ọ́ Ifa wipe nj ẹ́ oun le ni aya ìgbín naa bèèrè l ọ́ w ọ́ alawo r ẹ̀ wipe ńjẹ́ oun le ni ọk ọ awo ń ...

Saudando Exu, o Dono da Força

Imagem
  Meu salve a todos os amantes da língua e cultura iorubá! Meu nome é Professor Adelson Adéwalé de Brito popularmente conhecido como Mawo Adelson. Eu sou um Sacerdote (Líder) líder do Culto aos Voduns, religião que nossos compatriotas africanos trouxeram da costa ocidental da África para as América durante o período que durou a escravidão. Sou cidadão brasileiro, mas tenho orgulho de ser descendente de Anago. Faço parte da geração do povo Anago que foi trazido para este país há trezentos anos, durante o tráfico de escravos. Os Iorubas acreditam que o Todo-Poderoso enviou Ifá do céu para restaurar o mundo com sua Sabedoria. Antigamente, os anciãos Nagô costumavam dizer que antes de pedir qualquer cosa a Ifá, não devemos esquecer de pedir permissão a Exu.... Vamos saudar Exu (Treinem o Oriki original de saudação a Exu Laalu) O Ifa é um Orixá importante para o Culto a Ancestralidade, e é a personificação de um método filosófico para a orientação do modo de vida de cada...